.

Àrọko Alarinyan Jiyàn

1. Oríṣiríṣi àrọko ni ó wà nínú èdè Yorùbá. Àwọn náà ni wonyi

  • Àrọko oniroyin
  • Àrọko Aláayè
  • Àrọko Alapejuwe
  • Àrọko Alarinyan Jiyàn
  • Àrọko onisoro gbèsè.

2. Àpẹẹrẹ Àrọko Alarinyan Jiyàn ni wonyi

  • Ìṣe àgbè dára jù ìṣe dókítà lọ
  • Ijoba alágbára dára jù ijoba ologun lọ
  • Ọmọ obìnrin dára jù ọmọ ọkùnrin lọ
  • Ọmọ wunmi ju owó lọ
  • Ìgbà ojo dára jù ìgbà èérún lọ

Tags

2 comments

Leave a Reply

%d bloggers like this: